Gẹgẹbi awọn oniwun iṣowo, ọkan ninu awọn ibẹru nla wa ni sisọnu ohun gbogbo ti a ti ṣiṣẹ fun. Ododọ oro ni pe, o le ṣẹlẹ nigbakugba - ibesile ti ina, ole jija, ikun omi, ijamba ati bẹbẹ lọ.
Iṣeduro wa nibẹ lati rii daju wipe nigbati awọn iṣẹlẹ ailoriire wọnyi ba ṣẹlẹ, o koni padanu gbogbo ohun to ni, ati pe ni igba diẹ, gbo nkan a le pada si bi ose wa tele.
1. Ki lo mọ nipa iṣeduro?
2. Ki l'awọn ero re lori iṣeduro?
3. Kini awọn iriri ti o ti ni pẹlu ati lati iṣeduro?
4. Bawo ni iṣeduro ṣe n ṣiṣẹ ni otitọ??
Ti o ko ba mọ, iwọ ko mọ na niyen. A wa nibi lati rii daju pe o mọ ni pa iṣeduro ati awon anfani re. Eyi je ẹkọ ti o fanimora ati ti o rorun lori Iṣeduro ati Takaful. Kọ ẹkọ ati ṣiṣe iṣowo rẹ pẹlu ifọkanbalẹ.